You are on page 1of 1

AWURE ITAJA TABI AJO IBISE

Ewe arehinkosu, efun, osun, imi ojo, ikun


ojia, ao gun gbogbo re po, ao po mon ose ao
ko ose naa sinu fitila tuntun. Ao te ifa
ogudabede si ori re ao ma fi we.... OFO
RE........olugberede arinnakore ojinikutu gbe
apo oro dani, emi lagbaja nlo taja/lobise lonii,
bawo ni ntise lowo lowo, efun losope ki omo
araye fun mi lowo, osun losope ki omo araye
fire temi sunmi loni. Sebi tomode tagba ni
saanu arehinkosun, ki ina ola mi tan loniio

You might also like