You are on page 1of 6

Ògún

Akóro Ko l'axo Akóro no tiene ninguna ropa

Màrìwò l'axo Ògún o! Màrìwò lleva Ogún en su estrecha


relación con la naturaleza humana, que
Màrìwò Màrìwò es la regla de los "caminos" en el sentido
Ògún á jó (Ògún dançará) de trabajo, oportunidades profesionales
y en el mismo tiempo "guardián" de la
Iwó a gba 'lé bg'ònà casa, se expresa en su canción: y
màrìwò (frondas de Palma, utilizado
Ògún á jó e màrìwò màá tú yeyé como la ropa) Akòró y Ogún màrìwò (que
ocupará la casa y el camino) (hoja de
Akóro pa lónìí ó
Palma crecen) esta canción pide
Pa o jàre pa léle pa Abrimos caminos de Ogun : corte,
Ògún pa o jàre desenredar el camino. Otra traducción,
hablando de asesinato, cuando los
orishas llegó la guerra y lucharon. Ogun
utilizó una pequeña tiara (corona). Fue
permitido utilizar solamente una sola
diadema, llamada àkòró, y esto le valió
ser llamado, incluso hoy en día, bajo el
nombre de Aláàkòró Ògún (Señor de la
corona pequeña)

ogun laakaaye, oshin gbogbomole ogun d main warrior of all orisha, the man
ejemu oluwonran adigiri re bija who make a way for all orishas during their
lifetime ,an victorius man

Check

Ògún oh!! Ògún oh!!

Ògún onírè ọkọ ò mi Ògún god of iron, my husband


Irúnmolè tí ń rù mìnìmìnì
Òlómi nílé fèjè wè A deity that strikes heavily
Òlása nílé fìmọ̀bímọ̀ bora He has water at home, but bathes with
Ògún aládàá méjì blood
Ó fìkán sánko, ó fìkán yènà
Ojó Ògún ń fìkòlé òrun bò wá s'ílé ayé He has clothes, but wears palm fronds.
Asa iná ló mú bora
èwù èjè ló wọ̀ sọ́rùn o Ògún posessesses two cutlasses:
Ògún onílé owó ọlọ́nà ọla
Ògún onílé kángun kàngun òde òrun One for cutting grass, the other for making
Méje l'Ògún mi marks
Ògún alárá nií gbajá
Ògún onírè a gbàgbò Since Ògún came down from heaven to
Ògún ìkọlà a gbà 'gbín earth,
Ògún elémoná nií gbèsun asu He uses robes of fire as his cover,
Ògún akirun á gbà wo àgbò
Ògún gbénàgbénà eran ahun níí je A shirt of blood is what he puts on.
Ògún mákinde ti d'Ògún léhìn odi
Bí ò bá gba tápà á gbàbókí á gba Ògún has a house of riches, a house of
húnkùnhúnkùn wealth
á gba tèmbèrí o jàre
Ògún has a house of war in the great
Mo ní e má bógúnrún fìjà seré
beyond.
Ògún òlódodo l'Ògún tèmi
Ọmọ Orórínà, ọmọ Tàbúfú My god of iron is seven,
Morú nítorípé l'ójó Ògún kó délé ayé,
Emu ló kó bèrè o ḿgbà tó délè ìrè o Worshippers of Ògún bring him a dog.
Ògún onílé owó, Olónà olà
Ògún also accepts ram as a sacrifice.
Ògún ónile, kángunkàgun òde òrun
Mo ní e má aàbógùn fìjà sére o o The Ikola offer Ògún snails.
Ara Ògún kan gó gó gó
The Elemona offer roasted yam

The brave bring a ram.

The carpenter offers Ògún tree sap.

Mákinde, Ògún has become.

If he sells Tapa, he will sell his friend

He will collect three.

Eh! Do not use the sword to play with the


god of iron.

My Ògún is a truthful deity,

The son of Orórínà, son of Tàbúfú.

I tell you because, when Ògún came into


this world,

He asked first for palmwine when he got to


Ire.

Ògún´s house is full of money, His pathway


is full of wealth.

The owner of the ugly house in heaven,


I tell you, do not figth playfully with Ògún,

Ògún isn’t smiling at all.

Orì

Ori lo da mi Ori is my Creator


Eniyan ko o It is not man
Olodumare ni
It is Olodumare
Ori lo da mi
Ori is my Creator

Orunmila is the one who repairs such imperfect Orí. The following is anexcerpt from
an ancient Oriki, prayer poem, for Orunmila:

Odudu ti ndu Orí emere The one who saves those who are
Atun Orí ti ko suhan se destined to die young
A mo iku
The one whorepairs a bad Orí (Head)
Through your knowledge we
avertdeath

Iwure To Orí –
A Prayer For Good Luck and Blessings
Morning Prayer for Good Luck and Blessings
Bi o ba maa lowo If you want to have money
Beere lowo orii re Inquire of your head
Bi o ba maa sowo
If you want to start trading
Beere lowo Orí re wo
Inquire of your head
Bi o ba maa kole o
Beere lowo orii re If you want to build a house
Bi o ba maa laya o Inquire of your head
Beere lowo orii re wo If you want a relationship
Orí mase pekun de Inquire of your head first
Lodo re ni mi mbo Orí, my head, please do not shut the
Wa sayee fun awon omo mi di re
gate
It is you that I am coming to
Come and make my life prosperous

Ori Onise Èl Creador competente


Apere
Atete gbeni ju Orisa Apere
Ori atete niran
Él que es más rápido en ayudar a uno que el Orisa
Ori lokun
Ori nide El que recuerda instantáneamente a su devoto
Ko si Orisa ti dani gbe leyin
Ori eni Ori es valioso
Ori ni seni ta a fi dade owo
Ori ni seni ta a fi tepa ileke Ori es joyería
woja
No Orisa puede favorecer a uno sin el consentimiento de su
Ori ni seni ta a fi lo mosaaji
Ori
aso oba
Ori gbe mi Es Ori quien ayuda uno a uno a ser coronado de dinero
Ori la mi
Ori ma pada leyin miOr Es Ori quien bendice uno por uno para usar bastón de
cuentas incluso para el mercado

Es Ori quien bendice uno por uno para usar paños valiosos

Ori, por favor, apóyame

Ori, por favor, bendíceme

Ori, por favor, nunca te vuelvas contra mí

What is Ori?
Ori is the “Head”. Ori is an Orisa, and a very powerful and important one.
Odu Ifa Ogunda Meji teaches us:

Ko s’orisa ti i da ni i gbe lehin ori eni


No Orisa helps an individual without the consent of his or her Ori.

Also in Odu Ifa Ogunda Meji, IFA teaches us that Ori is the only Orisa that can be with us and
accompany us through all of life’s journeys.
Odu Ifa Irete Ofun teaches us:

Ko si Orisa to to nii gbe


Leyin Ori eni
Ori gbona j’Orisa

No other Orisa can give support


Outside of one’s Ori
Ori is higher than all Orisa.

Ase

We are born with Ori, but we also can (and should) receive the physical shrine for Ori.
Receiving Ori is a very powerful ceremony. Receiving Ori helps align one with their inner self
(Ori Inu) and with their higher self (Iponri).

IFA also says about Ori:

Orunmila lo dohun a-dun-hun-un Orunmila said complaint, complaint,


Emi naa lo dohun a-dun-hun-un complaint…
Orunmila ni begbe eni ba n lowo I said it is all complaint
Ba a ba a ti i ni in Orunmila said if ones colleagues are rich
Ifa ni ka ma dun huun-huun-huun If we are not yet rich
Ori elomii mo Ifa said we should not complain
Ori eni ni ka maa dun huun To another person’s Ori
Orunmila ni begbe eni ba n n’ire gbogbo We should complain to our own Ori
Ba a ba a ti I ni in Orunmila said if one’s colleagues are getting
Ori eni ni ka maa dun hun-un all the good things of life
Orii mi gbami If we have not got…
Mo dun huun aje mo o We should complain only to our Ori
Orii mi gbami My Ori, deliver me
Mo du huun ire gbogbo mo o I complain of money to you
Ori apere My Ori deliver me
a-sakara-moleke I complain of all the good things of life to you
eni Ori ba gbebo re Ori nicknamed apere. Nicknamed A-sakara-
ko yo sese moleke
Ase Whoever’s offering is accepted by their Ori
Should really rejoice

You might also like